×
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal

Gbigba Kadara gbọ (Èdè Yorùbá)

Itumọ igbagbọ si kadara pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah. Lẹyin naa idahun waye si ibeere yi: “ Njẹ a le fi kadara se ikẹwọ fun ẹsẹ dida bii?”

Play
معلومات المادة باللغة العربية