×

Nini Igbagbo si Ojo Ikehin (Èdè Yorùbá)

Pípèsè: Isa Akindele Solahudeen

Description

Olubanisoro se alaye lekunrere ohun ti a npe ni Ojo Ikehin ati awon orisirisi oruko ti Olohun Allah fun un ninu Alukuraani, Olubanisoro si tun se alaye awon nkan ti Ojo Igbehin ko sinu.

Download Book

معلومات المادة باللغة العربية